Ifeoluwa-artwork

“Ife Oluwa,” meaning “the love of God,” is a soul-stirring highlife fusion gospel song by ToLmusic that beautifully celebrates the profound love of God and His abundant blessings. This powerful track serves as a reminder that through Jesus Christ, we are adopted as His children, receiving new life and a fresh start. Featuring heartfelt performances by renowned gospel artists Juwon Omole and Mercy Sunday, “Ife Oluwa” is infused with genuine emotion and spiritual depth. Written by Tomayo Berida and expertly produced by Hosannie, this celebratory anthem of salvation was released during the Easter weekend, making it the perfect soundtrack for reflecting on the gift of grace. Discover the inspiring sounds of Nigerian gospel music with “Ife Oluwa.”

Stream Here

Watch Video Below:

IFEOLUWA SONG LYRICS
OLUGBALA F’EJE RA WA PADA
O SO WA DO MO O SI TUN WE WA MO
HALLELUJAH SÍ BABA TÓ F’OMO RÈ LÉ’LÈ
HALLELUJAH LO YE O, OBA WA OLORE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE

IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
OWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE

OLUTUNU TI NU’OMIJE MI NU
IBANU JE OJO’PIPE TI DI DUNNU
HALLELUJAH SI BABA TO’SORO MI DAYO
HALLELUJAH LO YE O, OBA MI OLORE
EMI YO MA KORIN OGO SI BABA MI LOKE
HALLELUJAH LO YE O OBA MI OLORE

IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE

O SO WA DI OMO
HALLELUJAH SÌ BABA
A RI IYE A RI IGBALA LOWO BABA WA
OLODUMARE O SE OLORUN WA

BABA TO BABA SE
O SE WA L’ORE O SO WA D’OMO
A RÍ IYE L’ODO RE BABA O

OLUTUNU TI NU’OMIJE WA NU
IBANUJE OJO’PIPE TI DI IDUNNU
HALLELUJAH SI BABA ONIBU ORE
HALLELUJAH LO YE O, OBA WA OLORE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O BABA WA OLORE

IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
IFE OLUWA SI WA OPO
IFE TI KO L’EGBE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE
AWA YO MA KORIN OGO SI BABA WA LOKE
HALLELUJAH LO YE O, BABA WA OLORE

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *